Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ + KJV àti kíkà pè̩lú fífi e̩se̩ tí ó ń kà hàn ní Yorùbá; ó tún ní Ató̩ka
Gbgbo ò̩rò̩ Bíbélì Yorùbá yìí - Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ (BMO) ni a fi àmì tí ó fi ìtumò̩ wo̩n hàn sí.
Ètò ìkò̩wè yìí lè ko̩ gbogbo ò̩rò̩ Jésù pè̩lú àwò̩ pupa.
O tún lè to Bíbélì Yorùbá àti ti Òyìnbó ètò ìkò̩wè yìí ní e̩se̩-e̩se̩, ní sísè̩ n̄ tè̩lé, tàbí ní ìsò̩rí-ìsò̩rí.
Isé̩ yìí jé̩ ogún The Word of God Bible Society, a KÒ sì gbo̩dò̩ dà á ko̩ fún e̩niké̩ni tàbí fún òré̩.
Lò ó bí i ìwé tí ó jé̩ wí pé e̩nìkans̩os̩o ni ó lè lò ó lé̩è̩kan. Má se lò ó ju nínú è̩ro̩ kan-s̩os̩o lo̩ lé̩è̩kan.
A kò fi àse̩ fún e̩niké̩ni láti s̩e àtúntè̩, tabí láti s̩e àdàko̩, tàbí láti tún Bíbélì Onítumò̩ tí a kà yìí kà sí inú kò̩pútà, tàbí kí á ká a sí inú kásé̩è̩tì (cassette), è̩ro̩ ìbánisò̩rò̩ alágbéká, è̩ro̩ orin alágbéká, tàbí CD/DVD, tàbí irúfé̩ e̩ro̩ tí a lè fi n̄ǹkan tàbí ò̩rò̩ pamó̩ sí; tàbí fún gbígbó̩ lòdì sí èrògbà ti irúfé̩ mìíran tí a so̩, tàbí tí a kò so̩ nígbà pínpín ò̩rò̩ Bíbelì yìí nigbà tí a pín in. E̩ni tí ó bá s̩e lòdì sí èyí fi hàn gban̄gba wí pé kò fé̩ ìtànká ìhìn rere.
Owó tí a bá rí nínú pín-pín Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ yìí ni a ń lò fún títèsíwájú ìpín-fún-ni ò̩rò̩ O̩ló̩run. Fi e̩nu kò pè̩lú ìlérí fún Jésù Krístì Olúwa wí pé o gba ètò Bíbélì yìí àti kíkà rè̩ ló̩nà è̩tó̩, àti wí pé o kò ní fi fún e̩niké̩ni ló̩nà àìtó̩.
A ń retí bí O̩ló̩run bá ti fi sí yín ní okàn: ò̩rò̩ ìgba-ni-ní-yànjú, ìrànló̩wó̩, è̩bùn, owó fún ètò Bíbélì yìí, tàbí ohun èlò fún àseyorí àti ìtè̩síwájú isé̩ Bíbélì Onítumò̩ yìí láti ò̩dò̩ yín.
===
The App contain cross-referenced KJV and Yorùbá Bibles; with Audio in English
All the words in the Yorùbá Bible called Bíbélì Mímó̩ Onítumò̩ (BMO) used in this App are fully accented to give their accurate meaning.
Jesus words can be shown in red letters in the App. You can arrange the wordings to present the Yorùbá and English Bibles in verses following one another or in paragraphs.
These files are the property of The Word of God Bible Society and may NOT be copied or shared with anyone or your friends.
Treat this file like a book; only one user at a time. Do NOT install on more than one device at a time.
This Bibeli Mimo Onitumo text and recordings for computers and Mp3 players should not be copied or stored in any format for any system known or unknown for storage or play-back. The instructions for the distribution medium should be strictly adhered to. The legally obtained copy can however be used in churches during services or for evangelism; for the blind, and those that cannot read. Anyone who violates these conditions shows that he does not want the propagation of the gospel.
The money raised on this Bible project is used for further distribution of the Word of God.
Advice, help and donations for these modules are welcome on any aspect of this project as God lays it on your heart.